Àgbérò Pythagoras
Jump to navigation
Jump to search

Àgbérò Pythagoras ninu mathematics, je ibasepo ninu Jeometri Euklid larin awon egbe meteta anigunmeta onigunrege. O so pe:
Ninu anigunmeta rege ti iba je, itobi alopomeji ti egbe re je hypotenusi (egbe ti o ko ju si igun rege) dogba mo aropo awon itobi awon alopomeji ti won je ti egbe meji to ku (egbe mejeji ti won pinu si ibi ti igun rege wa).
A le ko agbero yi sile gege bi asedogba:
nibiti c ti duro fun gigun hypotenusi, ti a ati b si duro fun awon gigun awon egbe meji to ku.